Nwando Achebe | |
---|---|
Orúkọ | Nwando Achebe |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | West Africanist, apìtàn àtenudẹ́nu, ajàfẹ́tọ́ obìnrin |
Ìjẹlógún gangan | Obinrin, ìtàn àtenudẹ́nu, ọ̀rọ̀ ilẹ̀ Áfríkà àti ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Afrika |
Nwando Achebe /θj/ (tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1970) jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti ajàfẹ́tọ́ obìnrin ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Òun ni adarí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ nípa kíkó ara ẹni mọ́ra ní College of Social Science[2] tí ilé-ìwé Michigan State University. Òun tún ni Akọ̀ròyìn àgbà fún Journal of West African History.[3]